Mo ti b'Oluwa ṣèlérí
Mo ti b'Oluwa pinnu
Pe láyé mi ti mo wa
Ki n maa sa se dànù
Láyé mi ti mo wa
Ki n ma sa se ri
Mo ti b'Oluwa pinnu.

Evergreen Ebenezer Obey❤️❤️❤️❤️❤️❤️

image